Jump to content

Àtòjọ àwọn olórin ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí. Ẹ lè wo àtòjọ ìpín àwọn orin orílẹ̀ èdè náà ní ẹ̀ka 'Nigerian musical groups'.

0-9[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

B[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

C[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • CDQ-olórin Ráàpù àti Olùkọrin
  • Chidinma -  olórin Pọ́ọ̀pù
  • Chike
  • Celestine Ukwu -  olórin Highlife

D[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

E[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Frank Edwards -  olórin gospel
  • Omotola Jalade Ekeinde - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
  • eLDee - olórin Ráàpù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
  • Emma Nyra - olórin R&B
  • Emmy Gee - olórin Ráàpù
  • Alhaji Dauda Epo-Àkàrà - Àwúrèbe

F[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Falz -  olórin Ráàpù àti Olùkọrin
  • Majek Fashek - olórin R&B àti Olùkọrinàti Olùkọrin
  • Faze -  olórin R&B
  • Flavour N'abania - olórin Pọ́ọ̀pù àti Highlife

G[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Tonye Garrick - olórin R&B àti Olùkọrin
  • Adekunle Gold - olórin àti Olùkọrin
  • Ruby Gyang

H[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Harrysong - olórin àti Olùkọrin
  • Humblesmith -olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù

I[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

J[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

K[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

L[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

M[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Mayorkun
  • M.I - olórin Ráàpù
  • M Trill -olórin Ráàpù
  • J. Martins - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
  • May7ven
  • Prince Nico Mbarga
  • Maud Meyer - olórin jáàsì
  • Mike Ejeagha - olórin Highlife
  • Mo'Cheddah -olórin Pọ́ọ̀pù
  • Mode 9 - olórin Ráàpù
  • Cynthia Morgan - olórin Pọ́ọ̀pù àti dacehall
  • Mr 2Kay
  • Mr Raw
  • Muma Gee - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
  • Muna - olórin Ráàpù
  • Muraina Oyelami

N[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

P[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Patoranking -  olórin régè àti dancehall
  • Pepenazi -  olórin Ráàpù, Pọ́ọ̀pù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
  • Peruzzi
  • Shina Peters - olórin Afro-Jùjú
  • Phyno - olórin Ráàpù ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
  • Praiz - olórin R&B àti Olùkọrin

R[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

S[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

T[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Tekno Miles - olórin Afro-Pọ́ọ̀pùolórin R&B àti Olùkọrin
  • Terry G - olórin R&B,  Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
  • Timaya - olórin régè
  • Tiwa Savage - olórin R&B àti Olùkọrin
  • Tony Tetuila-olórin R&B àti Olùkọrin

U[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Sir Victor Uwaifo - olórin highlife

W[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Waconzy - olórin Pọ́ọ̀pù
  • Waje
  • Eddy Wata
  • Weird MC - olórin Ráàpù
  • Wizkid - olórin Pọ́ọ̀pù

Y[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • YCEE - olórin Ráàpù
  • Yemi Blaq
  • Yung6ix - olórin Ráàpù

Z[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ̀ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Music of Nigeria

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]