Gbenga Ogedegbe
Gbenga Ogedegbe je dokita Naijiria ati ojogbon.[1][2]
Igbesi aye ni kutukutu[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ilu Eko ni won bi Ogedegbe. O lo si Hussey College, Warri. O pinnu lati di dokita ni omo odun mejo.[1] O lo si Donetsk National University ati Columbia University.[2]
Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ 1.0 1.1 "Dr. Gbenga Ogedegbe: Physician-Scientist, Barbershop Regular". NYU Langone. Archived from the original on 21 January 2021. Retrieved 4 October 2023.
- ↑ 2.0 2.1 "Dr. Gbenga Ogedegbe Biography". All American Speakers Bureau. Archived from the original on 12 March 2023. Retrieved 4 October 2023.